Olóògbé Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ (1909 - 1987), olósèlú, ọmọ orílẹ̀ èdè Naijiria
lati ẹ̀yà Yorùbá. Awólọ̀wọ̀ jẹ́ olórí fun awon omo ile Yoruba ati okan
ninu awon oloselu pataki ni orile ede Naijiria. A bi ni ojo kefa osu
keta odun 1909 ni Ikenne ni ipinle Ogun. Omo agbe ti o fi ise ati ogun
ise so ara re di omowe, Awolowo lo ile eko Anglican ati Methodist ni
Ikenne ati ni Baptist Boys' High School ni Abeokuta. Leyin re o lo si
Wesley College ni Ibadan ti o fi igba kan je oluilu Agbegbe Iwo Oorun
Orile ede Naijiria lati ba di Oluko. Ni odun 1934, o di olutaja ati
oniroyin. O se oludari ati alakoso Egbe Olutaja Awon Omo Naijiria
(Nigerian Produce Traders Association) ati akowe gbogbogbo Egbe Awon
Awako Igb'eru Omo Ile Naijiria (Nigerian Motor Transport Union).Omo
agbe ti o fi ise ati ogun ise so ara re di omowe, Awolowo lo ile eko
Anglican ati Methodist ni Ikenne ati ni Baptist Boys' High School ni
Abeokuta. Leyin re o lo si Wesley College ni Ibadan ti o fi igba kan
je oluilu Agbegbe Iwo Oorun Orile ede Naijiria lati ba di Oluko. Ni
odun 1934, o di olutaja ati oniroyin. O se oludari ati alakoso Egbe
Olutaja Awon Omo Naijiria (Nigerian Produce Traders Association) ati
akowe gbogbogbo Egbe Awon Awako Igb'eru Omo Ile Naijiria.
Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú Atlantis gbérá láti Kennedy Space Center fún ìfòlókè
STS-135 tó jẹ́ ìránlọṣe tó parí ètò Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú.
Ààrẹ Zine El Abidine Ben Ali sá kúrò ní Tunisia lẹ́yìn jàgídíjàgan tó
ṣẹlẹ̀ káàkiri orílẹ̀-èdè; Fouad Mebazaa di adípò Ààrẹ.
Gbogbo ìkọ wà lábẹ́ Creative Commons Attribution/Share-Alike License; ó
ṣe é ṣe kí àwọn ọ̀rọ̀ àdéhùn míràn tún wà. Ẹ wo Àwọn Ọ̀rọ̀ Àdéhùn Ìlò fún
ẹ̀kúnrẹ́rẹ́. 
Àdàkọ:GbogboẸ̀ka Àwọn èbúté àti ẹ̀ka àyọkà
